1 : Kí nǹkan má ṣòrò tàbí kí nǹkan má lọ dédé.: Ease f.a.: Ìdẹ̀rùn dé bá Adé bí ó ti ríṣẹ́ gbà. Things become easy for Ade after he was employed.
ì-dẹ̀-ọrùn
ì - the act of
dẹ̀ - relaxes
ọrùn - Neck
How could we have illustrated it better?
Most Popular