1 : Ẹ̀yí ni kí èèyàn máa tún ibìkan ṣe pàápàá jùlọ ibi tí ó dọ̀tí.: Tidying, cleaning up. f.a.: Ìpalẹ̀mọ́ inú ilé ìdáná ni à ń ṣe. We are tidying the kitchen.
2 : Èyí ni mímúrasílé fún ohun kan.: Preparing f.a.: Àná ni a ti bẹ̀rẹ̀ ìpalẹ̀mọ́ fún ìgbéyàwó náà. We have started preparing for the wedding since yesterday. f.a.: Ẹ kú ìpalẹ̀mọ́ ọdún. Happy preparations for the festivities.
Most Popular