ìtakùrọ̀sọ

Noun
ì-ta-kù-rọ̀-sọ | | GENERAL |

Definition of ìtakùrọ̀sọ 

1 : Èyí ni kí èèyàn méjì tàbí jùbẹ́ lọ máa jíròrò lórí orí ọ̀rọ̀ kannáà.: discussion f.a.: Èmi àti Olú jọ ní ìtakùrọ̀sọ ní àná. Olu and I had a discussion yesterday.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 11, 2026 and Submitted on November 10, 2026