ìtura

Noun
Ì-tu-ra | | GENERAL |

Definition of ìtura 

1 : Kí nǹkan ó dẹrùn pàápàá jùlọ lẹ́yìn ìgbà tí èèyàn ti la àwọn àkókò ìnira kọjá.: relief, comfort f.a.: Ìtura dé bá mi lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n bá mi wọ́ ẹsẹ̀ náà. I was relieved after my leg was massaged.

Morphology

ì-tura

Gloss

ì - the act of

tura - relief

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 10, 2026 and Submitted on November 09, 2026