ìwádǐ

Noun
ì-wá-dì-í | | GENERAL |

Definition of ìwádǐ 

1 : Ìlànà ṣíṣe àwárí àti kíkó ìsọfúnni jọ nípa ohun kan, ìṣẹ̀lẹ̀ kan, tàbí ọ̀ràn kan láti mọ òtítọ́ rẹ̀, lóye ohun tó ṣẹlẹ̀, tàbí rí ìdáhùn sí ìbéèrè kan.: investigation f.a.: Àwọn ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádǐ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà láti mọ ẹni tó ṣe é. The police began an investigation into the incident to identify the person responsible.

Morphology

ì-wá-ìdí

Gloss

ì - something that

wá - come, search

ìdí - buttocks, reason, rationale

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 08, 2026 and Submitted on November 05, 2026