1 Agbára ìmọ̀, ọgbọ́n, òye tó wà nínú ènìyàn láti lóye nǹkan, fura sí nǹkan láìṣe ìwádǐ tàbí ṣe ọ̀fíntótó kí èèyàn tó mọ òdòdo ọ̀rọ̀. intuition f.a.: Òye-inú mi sọ fún mi pé irọ́ ni ọmọ náà ń pa. My intuition told me that the child is lying.
Most Popular