1 : Ìfarahàn ìbínú, àìtẹ́lọ́rùn tàbí àtakò nípa ohun tí ènìyàn kò bá fẹ́ràn tàbí tí ó bá kà sí àìtọ́.: grievances, complaint f.a.: Àwọn òṣìṣẹ́ náà gbé ẹ̀hónú wọn lọ sí ọ̀dọ̀ olùdarí ilé-iṣẹ́ náà. The workers presented their grievances to the head of the company.
Most Popular