ẹ̀rọ-ìpẹyin

Noun
ẹ̀-rọ-ì-pẹ-yin | | GENERAL |

Definition of ẹ̀rọ-ìpẹyin 

1 : Ẹ̀rọ ìgbàlódé tí wọ́n máa ń kó ẹyin adìyẹ sí tó máa ń sọ ẹyin di ọmọ adìyẹ kẹ́kèèké: Incubator

2 : Ẹ̀rọ-ìpẹyin ti mú kí adìyẹ ṣínṣìn ó di ìrọ̀rùn nítorí pé ó máa ń pèṣè ọmọ adìyẹ lọ́pọ̀ yanturu.: Incubator has made chicken rearing easy because it used to produce day-old chicken in a large quantity.

Morphology

ẹ̀rọ-ìpẹyin

Gloss

ẹ̀rọ - machine, device, technology

ìpẹyin - that crack eggs

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 10, 2026 and Submitted on November 09, 2026