1 : Àyè ìta gbangba tí a yà sọ́tọ̀ láti ra ǹkan tàbí ta ǹkan.: An open place designated for buying and selling. f.a.: Ọjà Bódìjà ni mo ti ra ẹran. I bought meat from Bódìjà Market.
2 : Àwọn ẹrù tí èèyàn fẹ́ tà.: Goods one want to sell. f.a.: Ọjà yẹn wọ́n. Those goods are expensive.
Most Popular