ọbàkan

Noun
ọ-bà-kan | ɔbàkã | GENERAL |

Definition of ọbàkan 

1 : Èyí ni awọn ọmọ bàbá kan náà tí ó sì ṣé ṣe kí wọ́n má jẹ́ ọmọ ìyá kan náà.: Siblings of the same father but not necessarily of the same mother. f.a.: Ìfẹ́ àti ọbàkan mi pàdé ara wọn lọ́jà Akẹ̀sán My sibling of the same father and Ife met at Akesan market

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 19, 2026 and Submitted on November 16, 2026