ọlọ́dẹ

Noun
ọ-lọ́-dẹ | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of ọlọ́dẹ 

1 : Ẹni tí wọn gbà láti sọ ǹkan tàbí ibì kan.: Àwọn ọlọ́dẹ àdúgbò wa ń ṣiṣẹ́.

English Translation

A person employed to provide security for someone or something.

Example of ọlọ́dẹ 

a. Àwọn ọlọ́dẹ àdúgbò wa ń ṣiṣẹ́.

Morphology

oní-ọdẹ

Gloss

oní - ẹni tó ń ṣe ǹkan

ọdẹ - hunter, guard

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Submitted on February 16, 2026